Yoruba Nation National Anthem

Here is the Yoruba Nation National Anthem in Yoruba Language.

 

Ìṣe wa fún ilé wa
Fún ilé ibi wa
Ká gbé ga, ká gbé ga
Ká gbé ga f’aiye ri

 

Ìgbàgbọ́ wa ni pé
B’a ti b’ẹrú, là b’ọmọ
K’á ṣiṣẹ́, k’á ṣiṣẹ́
K’á ṣíṣe, k’a jọla.

 

Iṣọ̀kan àti Ominira
Ní k’ẹ jẹ́ ká máa lepa
‘Tesiwaju, f’ ọ̀pọ̀ ire
At’oun to dára

 

Ọmọ. Oodua dide
Bọ́ s’ipo ẹtọ́ rẹ́
Ìwọ ni imọ́lẹ̀
Ògo Adúláwọ.

 

Ilanauk
Management

Website Designing/Management/Social Media – Iyanu Victor

Follow Us On Telegram

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *